1
TẸSALONIKA KINNI 4:17
Yoruba Bible
A óo wá gbé àwa tí ó kù lẹ́yìn, tí a wà láàyè, lọ pẹlu wọn ninu awọsanma, láti lọ pàdé Oluwa ní òfuurufú, a óo sì máa wà lọ́dọ̀ Oluwa laelae.
Compare
Explore TẸSALONIKA KINNI 4:17
2
TẸSALONIKA KINNI 4:16
Nítorí nígbà tí ohùn àṣẹ bá dún, Olórí àwọn angẹli yóo fọhùn, fèrè Ọlọrun yóo dún, Oluwa fúnrarẹ̀ yóo sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run. Àwọn òkú ninu Jesu ni yóo kọ́kọ́ jinde.
Explore TẸSALONIKA KINNI 4:16
3
TẸSALONIKA KINNI 4:3-4
Nítorí ìfẹ́ Ọlọrun ni pé kí ẹ ya ara yín sí mímọ́: ẹ jìnnà sí àgbèrè. Kí ẹnìkọ̀ọ̀kan yín mọ ọ̀nà láti máa bá aya rẹ̀ gbé pọ̀ pẹlu ìwà mímọ́ ati iyì
Explore TẸSALONIKA KINNI 4:3-4
4
TẸSALONIKA KINNI 4:14
Nítorí bí a bá gbàgbọ́ pé Jesu kú, ó sì jinde, bẹ́ẹ̀ gan-an ni Ọlọrun yóo mú àwọn tí wọ́n ti kú ninu Jesu wà pẹlu rẹ̀.
Explore TẸSALONIKA KINNI 4:14
5
TẸSALONIKA KINNI 4:11
Ẹ gbìyànjú láti fi ọkàn yín balẹ̀. Ẹ má máa yọjú sí nǹkan oní-ǹkan. Ẹ tẹpá mọ́ṣẹ́, gẹ́gẹ́ bí a ti sọ fun yín.
Explore TẸSALONIKA KINNI 4:11
6
TẸSALONIKA KINNI 4:7
Nítorí Ọlọrun kò pè wá sí ìwà èérí bíkòṣe ìwà mímọ́.
Explore TẸSALONIKA KINNI 4:7
Home
Bible
Plans
Videos