1
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 6:3-4
Yoruba Bible
YCE
Nítorí náà, ẹ̀yin ará, ẹ wá ẹni meje láàrin yín, tí wọ́n ní orúkọ rere, tí wọ́n kún fún Ẹ̀mí Mímọ́ ati ọgbọ́n, kí á yàn wọ́n láti mójútó ètò yìí. Àwa ní tiwa, a óo tẹra mọ́ adura gbígbà ati iṣẹ́ iwaasu ọ̀rọ̀ ìyìn rere.”
Compare
Explore ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 6:3-4
2
ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 6:7
Ọ̀rọ̀ Ọlọrun wá ń gbilẹ̀. Iye àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu túbọ̀ ń pọ̀ sí i ní Jerusalẹmu. Pupọ ninu àwọn alufaa ni wọ́n sì di onigbagbọ.
Explore ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 6:7
Home
Bible
Plans
Videos