1
JOBU 37:5
Yoruba Bible
Ohùn Ọlọrun dún bí ààrá tìyanu-tìyanu, a kò lè rí ìdí iṣẹ́ ìyanu rẹ̀.
Compare
Explore JOBU 37:5
2
JOBU 37:23
Àwámárìídìí ni Olodumare– agbára ati ìdájọ́ òtítọ́ rẹ̀ pọ̀, bẹ́ẹ̀ ni kì í kọ òdodo sílẹ̀.
Explore JOBU 37:23
Home
Bible
Plans
Videos