1
ÌWÉ ÒWE 23:24
Yoruba Bible
Baba olódodo ọmọ yóo láyọ̀ pupọ, inú ẹni tí ó bí ọlọ́gbọ́n ọmọ yóo dùn.
Compare
Explore ÌWÉ ÒWE 23:24
2
ÌWÉ ÒWE 23:4
Má ṣe làálàá àṣejù láti kó ọrọ̀ jọ, fi ọgbọ́n sẹ́ ara rẹ.
Explore ÌWÉ ÒWE 23:4
3
ÌWÉ ÒWE 23:18
Dájúdájú, ọjọ́ ọ̀la rẹ yóo dára, ìrètí rẹ náà kò sì ní já sí òfo.
Explore ÌWÉ ÒWE 23:18
4
ÌWÉ ÒWE 23:17
Má ṣe ìlara àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, ṣugbọn máa bẹ̀rù OLUWA lọ́jọ́ gbogbo.
Explore ÌWÉ ÒWE 23:17
5
ÌWÉ ÒWE 23:13
Bá ọmọde wí; bí o bá fi pàṣán nà án, kò ní kú.
Explore ÌWÉ ÒWE 23:13
6
ÌWÉ ÒWE 23:12
Fi ọkàn rẹ sí ẹ̀kọ́, kí o sì tẹ́tí sí ọ̀rọ̀ ìmọ̀.
Explore ÌWÉ ÒWE 23:12
7
ÌWÉ ÒWE 23:5
Kí o tó ṣẹ́jú pẹ́, owó rẹ lè ti lọ, ó le gúnyẹ̀ẹ́ kí ó fò, bí ìgbà tí ẹyẹ àṣá bá fò lọ.
Explore ÌWÉ ÒWE 23:5
8
ÌWÉ ÒWE 23:22
Gbọ́ ti baba tí ó bí ọ, má sì ṣe pẹ̀gàn ìyá rẹ nígbà tí àgbà bá dé sí i.
Explore ÌWÉ ÒWE 23:22
Home
Bible
Plans
Videos