1
ORIN DAFIDI 105:1
Yoruba Bible
Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, ẹ pe orúkọ rẹ̀, ẹ fi iṣẹ́ rẹ̀ hàn ní gbogbo orílẹ̀-èdè.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 105:1
2
ORIN DAFIDI 105:4
Ẹ wá ojurere OLUWA ati agbára rẹ̀, ẹ máa wá ojurere rẹ̀ nígbà gbogbo.
Explore ORIN DAFIDI 105:4
3
ORIN DAFIDI 105:3
Ẹ máa fi orúkọ mímọ́ rẹ̀ yangàn, kí ọkàn àwọn tí ń wá OLUWA ó máa yọ̀.
Explore ORIN DAFIDI 105:3
4
ORIN DAFIDI 105:2
Ẹ kọrin sí i, ẹ kọ orin ìyìn sí i, ẹ sọ nípa gbogbo iṣẹ́ ribiribi rẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 105:2
Home
Bible
Plans
Videos