1
ORIN DAFIDI 11:7
Yoruba Bible
Nítorí olódodo ni OLUWA, ó sì fẹ́ràn òdodo; àwọn olóòótọ́ ni yóo rí ojú rẹ̀.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 11:7
2
ORIN DAFIDI 11:4
OLUWA ń bẹ ninu tẹmpili mímọ́ rẹ̀, ìtẹ́ rẹ̀ wà lọ́run; OLUWA ń kíyèsí àwọn ọmọ eniyan, ó sì ń yẹ̀ wọ́n wò.
Explore ORIN DAFIDI 11:4
3
ORIN DAFIDI 11:5
OLUWA ń yẹ àwọn olódodo, ati eniyan burúkú wò, ṣugbọn tọkàntọkàn ni ó kórìíra àwọn tí ó fẹ́ràn ìwà ipá.
Explore ORIN DAFIDI 11:5
4
ORIN DAFIDI 11:3
Nígbà tí ìpìlẹ̀ bá bàjẹ́, kí ni olódodo lè ṣe?”
Explore ORIN DAFIDI 11:3
5
ORIN DAFIDI 11:1
OLUWA ni mo sá di; ẹ ṣe lè wí fún mi pé, “Fò lọ sórí òkè bí ẹyẹ
Explore ORIN DAFIDI 11:1
Home
Bible
Plans
Videos