1
ORIN DAFIDI 118:24
Yoruba Bible
Òní ni ọjọ́ tí OLUWA dá, ẹ jẹ́ kí á máa yọ̀, kí inú wa sì máa dùn.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 118:24
2
ORIN DAFIDI 118:6
Nígbà tí OLUWA wà pẹlu mi, ẹ̀rù kò bà mí. Kí ni eniyan lè fi mí ṣe?
Explore ORIN DAFIDI 118:6
3
ORIN DAFIDI 118:8
Ó sàn láti sá di OLUWA, ju ati gbẹ́kẹ̀lé eniyan lọ.
Explore ORIN DAFIDI 118:8
4
ORIN DAFIDI 118:5
Ninu ìpọ́njú, mo ké pe OLUWA, ó dá mi lóhùn, ó sì tú mi sílẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 118:5
5
ORIN DAFIDI 118:29
Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, nítorí pé ó ṣeun, nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.
Explore ORIN DAFIDI 118:29
6
ORIN DAFIDI 118:1
Explore ORIN DAFIDI 118:1
7
ORIN DAFIDI 118:14
OLUWA ni agbára ati orin mi, ó ti di olùgbàlà mi.
Explore ORIN DAFIDI 118:14
8
ORIN DAFIDI 118:9
Ó sàn láti sá di OLUWA, ju ati gbẹ́kẹ̀lé àwọn ìjòyè.
Explore ORIN DAFIDI 118:9
9
ORIN DAFIDI 118:22
Òkúta tí àwọn ọ̀mọ̀lé kọ̀ sílẹ̀, ni ó di pataki igun ilé.
Explore ORIN DAFIDI 118:22
Home
Bible
Plans
Videos