1
ORIN DAFIDI 13:5
Yoruba Bible
Ṣùgbọ́n èmi gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀; n óo máa yọ̀ nítorí pé o óo gbà mí.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 13:5
2
ORIN DAFIDI 13:6
N óo máa kọrin sí ọ, OLUWA, nítorí o ṣeun fún mi lọpọlọpọ.
Explore ORIN DAFIDI 13:6
3
ORIN DAFIDI 13:1
Yóo ti pẹ́ tó, OLUWA? Ṣé o óo wá gbàgbé mi laelae ni? Títí di ìgbà wo ni o óo fi ojú pamọ́ fún mi?
Explore ORIN DAFIDI 13:1
4
ORIN DAFIDI 13:2
Títí di ìgbà wo ni ọkàn mi yóo gbọgbẹ́ tí ìbànújẹ́ yóo gba ọkàn mi kan, ní gbogbo ìgbà? Títí di ìgbà wo ni àwọn ọ̀tá mi yóo máa yọ̀ mí?
Explore ORIN DAFIDI 13:2
Home
Bible
Plans
Videos