1
ORIN DAFIDI 16:11
Yoruba Bible
O ti fi ọ̀nà ìyè hàn mí; ayọ̀ kíkún ń bẹ ní iwájú rẹ, ìgbádùn àìlópin sì ń bẹ ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 16:11
2
ORIN DAFIDI 16:8
Mò ń wo OLUWA ní iwájú mi nígbà gbogbo, nítorí pé Ọlọrun dúró tì mí, ẹsẹ̀ mi kò ní yẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 16:8
3
ORIN DAFIDI 16:5
OLUWA, ìwọ ni ìpín mi, ìwọ ni mo yàn; ìwọ ni ò ń jẹ́ kí ọ̀ràn mi fìdí múlẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 16:5
4
ORIN DAFIDI 16:7
Èmi óo máa yin OLUWA, ẹni tí ó ń fún mi ní òye; ọkàn mi ó sì máa tọ́ mi sọ́nà ní òròòru.
Explore ORIN DAFIDI 16:7
5
ORIN DAFIDI 16:6
Ìpín tí ó bọ́ sí mi lọ́wọ́ dára pupọ; ogún rere ni ogún ti mo jẹ.
Explore ORIN DAFIDI 16:6
6
ORIN DAFIDI 16:1
Pa mí mọ́ Ọlọrun, nítorí ìwọ ni mo sá di.
Explore ORIN DAFIDI 16:1
Home
Bible
Plans
Videos