1
ORIN DAFIDI 20:7
Yoruba Bible
Àwọn mìíràn gbẹ́kẹ̀lé kẹ̀kẹ́ ogun, àwọn mìíràn gbẹ́kẹ̀lé ẹṣin, ṣugbọn ní tiwa, àwa gbẹ́kẹ̀lé orúkọ OLUWA Ọlọrun wa.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 20:7
2
ORIN DAFIDI 20:4
Yóo fún ọ ní ohun tí o fẹ́ ninu ọkàn rẹ, yóo sì mú gbogbo èrò rẹ ṣẹ.
Explore ORIN DAFIDI 20:4
3
ORIN DAFIDI 20:1
OLUWA óo dá ọ lóhùn ní ọjọ́ ìpọ́njú, orúkọ Ọlọrun Jakọbu óo dáàbò bò ọ́.
Explore ORIN DAFIDI 20:1
4
ORIN DAFIDI 20:5
Ìhó ayọ̀ ni a óo hó nígbà tí o bá ṣẹgun, ní orúkọ Ọlọrun wa ni a óo sì fi ọ̀págun wa sọlẹ̀; OLUWA yóo dáhùn gbogbo ìbéèrè rẹ.
Explore ORIN DAFIDI 20:5
Home
Bible
Plans
Videos