1
ORIN DAFIDI 34:18
Yoruba Bible
OLUWA wà nítòsí àwọn tí ọkàn wọn bàjẹ́, a sì máa gba àwọn oníròbìnújẹ́ ọkàn là.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 34:18
2
ORIN DAFIDI 34:4
Mo ké pe OLUWA, ó sì dá mi lóhùn, ó sì gbà mí lọ́wọ́ gbogbo ohun tí ń bà mí lẹ́rù.
Explore ORIN DAFIDI 34:4
3
ORIN DAFIDI 34:19
Ìpọ́njú olódodo a máa pọ̀; ṣugbọn OLUWA a máa kó o yọ ninu gbogbo wọn.
Explore ORIN DAFIDI 34:19
4
ORIN DAFIDI 34:8
Tọ́ ọ wò, kí o sì rí i pé rere ni OLUWA! Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí ó bá sá di í!
Explore ORIN DAFIDI 34:8
5
ORIN DAFIDI 34:5
Wọ́n gbójú sókè sí OLUWA, wọ́n láyọ̀; ojú kò sì tì wọ́n.
Explore ORIN DAFIDI 34:5
6
ORIN DAFIDI 34:17
Nígbà tí olódodo bá kígbe fún ìrànlọ́wọ́, OLUWA a máa gbọ́, a sì máa gbà wọ́n kúrò ninu gbogbo ìyọnu wọn.
Explore ORIN DAFIDI 34:17
7
ORIN DAFIDI 34:7
Angẹli OLUWA yí àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀ ká, a sì máa gbà wọ́n.
Explore ORIN DAFIDI 34:7
8
ORIN DAFIDI 34:14
Ẹ yàgò fún ibi, rere ni kí ẹ máa ṣe; ẹ máa wá alaafia, kí ẹ sì máa lépa rẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 34:14
9
ORIN DAFIDI 34:13
Ẹ ṣọ́ ẹnu yín, ẹ má sọ̀rọ̀ burúkú, ẹ má sì jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn ti ẹnu yín jáde.
Explore ORIN DAFIDI 34:13
10
ORIN DAFIDI 34:15
OLUWA ń ṣọ́ àwọn olódodo, Ó sì ń dẹ etí sí igbe wọn.
Explore ORIN DAFIDI 34:15
11
ORIN DAFIDI 34:3
Ẹ bá mi gbé OLUWA ga, ẹ jẹ́ kí á jùmọ̀ gbé orúkọ rẹ̀ lékè!
Explore ORIN DAFIDI 34:3
Home
Bible
Plans
Videos