1
ORIN DAFIDI 5:12
Yoruba Bible
Nítorí ìwọ OLUWA a máa bukun àwọn olódodo; ò sì máa fi ojurere rẹ tí ó dàbí apata dáàbò bò wọ́n.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 5:12
2
ORIN DAFIDI 5:3
OLUWA, o óo gbọ́ ohùn mi ní òwúrọ̀, ní òwúrọ̀ ni n óo máa sọ ẹ̀dùn ọkàn mi fún ọ; èmi óo sì máa ṣọ́nà.
Explore ORIN DAFIDI 5:3
3
ORIN DAFIDI 5:11
Ṣugbọn jẹ́ kí inú gbogbo àwọn tí ó sá di ọ́ ó dùn, kí wọn ó máa kọrin ayọ̀ títí lae. Dáàbò bò wọ́n, kí àwọn tí ó fẹ́ràn orúkọ rẹ sì máa yọ̀ ninu rẹ.
Explore ORIN DAFIDI 5:11
4
ORIN DAFIDI 5:8
OLUWA, tọ́ mi sọ́nà òdodo rẹ, nítorí àwọn ọ̀tá mi; jẹ́ kí ọ̀nà rẹ hàn kedere níwájú mi.
Explore ORIN DAFIDI 5:8
5
ORIN DAFIDI 5:2
Fetí sí igbe mi, Ọba mi ati Ọlọrun mi, nítorí ìwọ ni mò ń gbadura sí.
Explore ORIN DAFIDI 5:2
Home
Bible
Plans
Videos