1
ORIN DAFIDI 67:1
Yoruba Bible
Kí Ọlọrun óo ṣàánú wa, kí ó bukun wa; kí ojú rẹ̀ tan ìmọ́lẹ̀ sí wa lára
Compare
Explore ORIN DAFIDI 67:1
2
ORIN DAFIDI 67:7
Ọlọrun bukun wa, kí gbogbo ayé máa bẹ̀rù rẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 67:7
3
ORIN DAFIDI 67:4
Kí inú àwọn orílẹ̀-èdè ó dùn, kí wọn ó máa kọrin ayọ̀, nítorí pé ò ń ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan láìṣe ojuṣaaju; o sì ń tọ́ gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè ayé.
Explore ORIN DAFIDI 67:4
Home
Bible
Plans
Videos