1
ORIN DAFIDI 77:11-12
Yoruba Bible
N óo ranti àwọn iṣẹ́ OLUWA, àní, n óo ranti àwọn iṣẹ́ ìyanu ìgbàanì. N óo máa ṣe àṣàrò lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ; n óo sì máa ronú lórí àwọn iṣẹ́ ribiribi tí o ṣe.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 77:11-12
2
ORIN DAFIDI 77:14
Ìwọ ni Ọlọrun tí ń ṣe ohun ìyanu; o ti fi agbára rẹ hàn láàrin àwọn eniyan.
Explore ORIN DAFIDI 77:14
3
ORIN DAFIDI 77:13
Ọlọrun, mímọ́ ni ọ̀nà rẹ; oriṣa wo ni ó tó Ọlọrun wa?
Explore ORIN DAFIDI 77:13
4
ORIN DAFIDI 77:1-2
Mo ké pe Ọlọrun fún ìrànlọ́wọ́, mo kígbe pe Ọlọrun kí ó lè gbọ́ tèmi. Ní ọjọ́ ìpọ́njú mi, mo wá OLUWA; ní òru, mo tẹ́wọ́ adura láìkáàárẹ̀, ṣugbọn n kò rí ìtùnú.
Explore ORIN DAFIDI 77:1-2
Home
Bible
Plans
Videos