1
ORIN DAFIDI 86:11
Yoruba Bible
OLUWA, kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ, kí n lè máa rìn ninu òtítọ́ rẹ; kí n lè pa ọkàn pọ̀ láti máa bẹ̀rù orúkọ rẹ.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 86:11
2
ORIN DAFIDI 86:5
Nítorí pé olóore ni ọ́, OLUWA, o máa ń dárí jini; ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ sì pọ̀ sí gbogbo àwọn tí ń ké pè ọ́.
Explore ORIN DAFIDI 86:5
3
ORIN DAFIDI 86:15
Ṣugbọn ìwọ, OLUWA, ni Ọlọrun aláàánú ati olóore; o kì í tètè bínú, o sì kún fún ìfẹ́ tí kì í yẹ̀, ati òtítọ́.
Explore ORIN DAFIDI 86:15
4
ORIN DAFIDI 86:12
Gbogbo ọkàn ni mo fi dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, OLUWA, Ọlọrun mi; n óo máa yin orúkọ rẹ lógo títí lae.
Explore ORIN DAFIDI 86:12
5
ORIN DAFIDI 86:7
Ní ọjọ́ ìpọ́njú mo ké pè ọ́, nítorí pé o máa ń gbọ́ adura mi.
Explore ORIN DAFIDI 86:7
Home
Bible
Plans
Videos