1
ORIN DAFIDI 92:12-13
Yoruba Bible
Àwọn olódodo yóo gbilẹ̀ bí igi ọ̀pẹ, wọn óo dàgbà bí igi kedari ti Lẹbanoni. Wọ́n dàbí igi tí a gbìn sí ilé OLUWA, tí ó sì ń dàgbà ninu àgbàlá Ọlọrun wa.
Compare
Explore ORIN DAFIDI 92:12-13
2
ORIN DAFIDI 92:14-15
Wọn á máa so èso títí di ọjọ́ ogbó wọn, wọn á máa lómi lára, ewé wọn á sì máa tutù nígbà gbogbo; láti fihàn pé olóòótọ́ ni OLUWA; òun ni àpáta mi, kò sì sí aiṣododo lọ́wọ́ rẹ̀.
Explore ORIN DAFIDI 92:14-15
Home
Bible
Plans
Videos