1
I. Kor 10:13
Bibeli Mimọ
Kò si idanwò kan ti o ti ibá nyin, bikoṣe irú eyiti o mọ niwọn fun enia: ṣugbọn olododo li Ọlọrun, ẹniti kì yio jẹ ki a dan nyin wò jù bi ẹnyin ti le gbà; ṣugbọn ti yio si ṣe ọna atiyọ pẹlu ninu idanwò na, ki ẹnyin ki o ba le gbà a.
Compare
Explore I. Kor 10:13
2
I. Kor 10:31
Nitorina bi ẹnyin ba njẹ, tabi bi ẹnyin ba nmu, tabi ohunkohun ti ẹnyin ba nṣe, ẹ mã ṣe gbogbo wọn fun ogo Ọlọrun.
Explore I. Kor 10:31
3
I. Kor 10:12
Nitorina ẹniti o ba rò pe on duro, ki o kiyesara, ki o má ba ṣubu.
Explore I. Kor 10:12
4
I. Kor 10:23
Ohun gbogbo li o yẹ fun mi, ṣugbọn ki iṣe ohun gbogbo li o li ere; ohun gbogbo li o yẹ fun mi, ṣugbọn kì iṣe ohun gbogbo ni igbé-ni-ró.
Explore I. Kor 10:23
5
I. Kor 10:24
Ki ẹnikẹni máṣe mã wá ti ara rẹ̀, ṣugbọn ki olukuluku mã wá ire ọmọnikeji rẹ̀.
Explore I. Kor 10:24
Home
Bible
Plans
Videos