1
II. Tim 2:15
Bibeli Mimọ
Ṣãpọn lati fi ara rẹ hàn niwaju Ọlọrun li ẹniti o yege, aṣiṣẹ́ ti kò ni lati tiju, ti o npín ọ̀rọ otitọ bi o ti yẹ.
Compare
Explore II. Tim 2:15
2
II. Tim 2:22
Mã sá fun ifẹkufẹ ewe: si mã lepa ododo, igbagbọ́, ifẹ, alafia, pẹlu awọn ti nkepè Oluwa lati inu ọkàn funfun wá.
Explore II. Tim 2:22
3
II. Tim 2:24
Iranṣẹ Oluwa kò si gbọdọ jà; bikoṣe ki o jẹ ẹni pẹlẹ si enia gbogbo, ẹniti o le kọ́ni, onisũru
Explore II. Tim 2:24
4
II. Tim 2:13
Bi awa kò ba gbagbọ́, on duro li olõtọ: nitori on kò le sẹ́ ara rẹ̀.
Explore II. Tim 2:13
5
II. Tim 2:25
Ẹniti yio mã kọ́ awọn aṣodi pẹlu iwa tutu; boya Ọlọrun le fun wọn ni ironupiwada si imọ otitọ
Explore II. Tim 2:25
6
II. Tim 2:16
Ṣugbọn yà kuro ninu ọ̀rọ asan, nitoriti nwọn ó mã lọ siwaju ninu aiwa-bi-Ọlọrun
Explore II. Tim 2:16
Home
Bible
Plans
Videos