1
Gẹn 30:22
Bibeli Mimọ
Ọlọrun si ranti Rakeli, Ọlọrun si gbọ́ tirẹ̀, o si ṣí i ni inu.
Compare
Explore Gẹn 30:22
2
Gẹn 30:24
O si pè orukọ rẹ̀ ni Josefu; o si wipe, Ki OLUWA ki o fi ọmọkunrin kan kún u fun mi pẹlu.
Explore Gẹn 30:24
3
Gẹn 30:23
O si yún, o si bí ọmọkunrin kan; o si wipe, Ọlọrun mú ẹ̀gan mi kuro
Explore Gẹn 30:23
Home
Bible
Plans
Videos