1
Isa 32:17
Bibeli Mimọ
Iṣẹ ododo yio si jẹ alafia, ati eso ododo yio jẹ idakẹjẹ on ãbo titi lai.
Compare
Explore Isa 32:17
2
Isa 32:18
Awọn enia mi yio si ma gbe ibugbe alafia, ati ni ibugbe idaniloju, ati ni ibi isimi iparọrọ
Explore Isa 32:18
Home
Bible
Plans
Videos