1
Job 19:25
Bibeli Mimọ
Ati emi, emi mọ̀ pe Oludande mi mbẹ li ãyè, ati pe on bi Ẹni-ikẹhin ni yio dide soke lori erupẹ ilẹ.
Compare
Explore Job 19:25
2
Job 19:27
Ẹniti emi o ri fun ara mi, ti oju mi o si wò, kì si iṣe ti ẹlomiran; ọkàn mi si dáku ni inu mi.
Explore Job 19:27
Home
Bible
Plans
Videos