1
File 1:6
Bibeli Mimọ
Ki idapọ igbagbọ́ rẹ le lagbara, ni imọ ohun rere gbogbo ti mbẹ ninu nyin si Kristi.
Compare
Explore File 1:6
2
File 1:7
Emi sá ni ayọ̀ pupọ ati itunu nitori ifẹ rẹ, nitoriti a tù ọkàn awọn enia mimọ́ lara lati ọwọ́ rẹ wá, arakunrin.
Explore File 1:7
3
File 1:4
Emi ndupẹ lọwọ Ọlọrun mi nigbagbogbo, emi nṣe iranti rẹ ninu adura mi
Explore File 1:4
Home
Bible
Plans
Videos