1
Owe 22:6
Bibeli Mimọ
Tọ́ ọmọde li ọ̀na ti yio tọ̀: nigbati o si dàgba tan, kì yio kuro ninu rẹ̀.
Compare
Explore Owe 22:6
2
Owe 22:4
Ere irẹlẹ ati ibẹ̀ru Oluwa li ọrọ̀, ọlá, ati ìye.
Explore Owe 22:4
3
Owe 22:1
ORUKỌ rere sàn ni yiyàn jù ọrọ̀ pupọ lọ, ati ojurere ifẹ jù fadaka ati wura lọ.
Explore Owe 22:1
4
Owe 22:24
Máṣe ba onibinu enia ṣe ọrẹ́; má si ṣe ba ọkunrin oninu-fùfu rìn.
Explore Owe 22:24
5
Owe 22:9
Ẹniti o li oju ãnu li a o bukun fun; nitoriti o fi ninu onjẹ rẹ̀ fun olupọnju.
Explore Owe 22:9
6
Owe 22:3
Ọlọgbọ́n enia ti ri ibi tẹlẹ, o si pa ara rẹ̀ mọ́: ṣugbọn awọn òpe a kọja, a si jẹ wọn niya.
Explore Owe 22:3
7
Owe 22:7
Ọlọrọ̀ ṣe olori olupọnju, ajigbese si ṣe iranṣẹ fun onigbese.
Explore Owe 22:7
8
Owe 22:2
Ọlọrọ̀ ati talaka pejọ pọ̀: Oluwa li ẹlẹda gbogbo wọn.
Explore Owe 22:2
9
Owe 22:22-23
Máṣe ja talaka li ole, nitori ti iṣe talaka: bẹ̃ni ki o má si ṣe ni olupọnju lara ni ibode: Nitori Oluwa yio gbija wọn, yio si gbà ọkàn awọn ti ngbà lọwọ wọn.
Explore Owe 22:22-23
Home
Bible
Plans
Videos