1
Owe 7:2-3
Bibeli Mimọ
Pa ofin mi mọ́, ki iwọ ki o si yè; ati aṣẹ mi bi ọmọloju rẹ. Dì wọn mọ ika rẹ, kọ wọn si wala aiya rẹ.
Compare
Explore Owe 7:2-3
2
Owe 7:1
ỌMỌ mi, pa ọ̀rọ mi mọ́, ki o si fi ofin mi ṣe ìṣura pẹlu rẹ.
Explore Owe 7:1
3
Owe 7:5
Ki nwọn ki o le pa ọ mọ́ kuro lọwọ obinrin ẹlomiran, lọwọ ajeji ti nfi ọ̀rọ rẹ̀ ṣe ipọnni.
Explore Owe 7:5
Home
Bible
Plans
Videos