1
O. Daf 145:18
Bibeli Mimọ
YBCV
Oluwa wà leti ọdọ gbogbo awọn ti nkepè e, leti ọdọ gbogbo ẹniti nkepè e li otitọ.
Compare
Explore O. Daf 145:18
2
O. Daf 145:8
Olore-ọfẹ li Oluwa, o kún fun ãnu; o lọra lati binu, o si li ãnu pupọ̀.
Explore O. Daf 145:8
3
O. Daf 145:9
Oluwa ṣeun fun ẹni gbogbo; iyọ́nu rẹ̀ si mbẹ lori iṣẹ rẹ̀ gbogbo.
Explore O. Daf 145:9
4
O. Daf 145:3
Titobi li Oluwa, o si ni iyìn pupọ̀-pupọ̀; awamaridi si ni titobi rẹ̀.
Explore O. Daf 145:3
5
O. Daf 145:13
Ijọba rẹ ijọba aiye-raiye ni, ati ijọba rẹ lati iran-diran gbogbo.
Explore O. Daf 145:13