1
O. Daf 147:3
Bibeli Mimọ
YBCV
O mu awọn onirora aiya lara da: o di ọgbẹ wọn
Compare
Explore O. Daf 147:3
2
O. Daf 147:11
Oluwa nṣe inudidùn si awọn ti o bẹ̀ru rẹ̀, si awọn ti nṣe ireti ãnu rẹ̀.
Explore O. Daf 147:11
3
O. Daf 147:5
Oluwa wa tobi, ati alagbara nla: oye rẹ̀ kò li opin.
Explore O. Daf 147:5
4
O. Daf 147:4
O ka iye awọn ìrawọ; o si sọ gbogbo wọn li orukọ.
Explore O. Daf 147:4
5
O. Daf 147:6
Oluwa gbé awọn onirẹlẹ soke: o rẹ̀ awọn enia buburu si ilẹyilẹ.
Explore O. Daf 147:6