1
O. Daf 23:4
Bibeli Mimọ
Nitõtọ, bi mo tilẹ nrìn larin afonifoji ojiji ikú, emi kì yio bẹ̀ru ibi kan; nitori ti Iwọ pẹlu mi; ọgọ rẹ ati ọpá rẹ nwọn ntù mi ninu.
Compare
Explore O. Daf 23:4
2
O. Daf 23:1
OLUWA li Oluṣọ-agutan mi; emi kì yio ṣe alaini.
Explore O. Daf 23:1
3
O. Daf 23:6
Nitotọ, ire ati ãnu ni yio ma tọ̀ mi lẹhin li ọjọ aiye mi gbogbo; emi o si ma gbe inu ile Oluwa lailai.
Explore O. Daf 23:6
4
O. Daf 23:2-3
O mu mi dubulẹ ninu papa-oko tutù; o mu mi lọ si iha omi didakẹ rọ́rọ́. O tù ọkàn mi lara; o mu mi lọ nipa ọ̀na ododo nitori orukọ rẹ̀.
Explore O. Daf 23:2-3
Home
Bible
Plans
Videos