1
O. Daf 25:5
Bibeli Mimọ
Sin mi li ọ̀na otitọ rẹ, ki o si kọ́ mi: nitori iwọ li Ọlọrun igbala mi; iwọ ni mo duro tì li ọjọ gbogbo.
Compare
Explore O. Daf 25:5
2
O. Daf 25:4
Fi ọ̀na rẹ hàn mi, Oluwa; kọ́ mi ni ipa tirẹ.
Explore O. Daf 25:4
3
O. Daf 25:14
Aṣiri Oluwa wà pẹlu awọn ti o bẹ̀ru rẹ̀, yio si fi wọn mọ̀ majẹmu rẹ̀.
Explore O. Daf 25:14
4
O. Daf 25:7
Máṣe ranti ẹ̀ṣẹ igba-ewe mi, ati irekọja mi: gẹgẹ bi ãnu rẹ iwọ ranti mi, Oluwa, nitori ore rẹ
Explore O. Daf 25:7
5
O. Daf 25:3
Lõtọ, maṣe jẹ ki oju ki o tì ẹnikẹni ti o duro tì ọ: awọn ti nṣẹ̀ li ainidi ni oju yio tì.
Explore O. Daf 25:3
Home
Bible
Plans
Videos