1
O. Daf 31:24
Bibeli Mimọ
Ẹ tujuka, yio si mu nyin li aiya le, gbogbo ẹnyin ti o ni ireti niti Oluwa.
Compare
Explore O. Daf 31:24
2
O. Daf 31:15
Igba mi mbẹ li ọwọ rẹ: gbà mi li ọwọ awọn ọta mi, ati li ọwọ awọn ti nṣe inunibini si mi
Explore O. Daf 31:15
3
O. Daf 31:19
Ore rẹ ti tobi to, ti iwọ fi ṣura dè awọn ti o bẹru rẹ: ore ti iwọ ti ṣe fun awọn ti o gbẹkẹle ọ niwaju awọn ọmọ enia!
Explore O. Daf 31:19
4
O. Daf 31:14
Ṣugbọn emi gbẹkẹle ọ, Oluwa: emi ni, Iwọ li Ọlọrun mi.
Explore O. Daf 31:14
5
O. Daf 31:3
Nitori iwọ li apata mi ati odi mi: nitorina nitori orukọ rẹ ma ṣe itọ́ mi, ki o si ma ṣe amọ̀na mi.
Explore O. Daf 31:3
6
O. Daf 31:5
Li ọwọ rẹ ni mo fi ẹmi mi le: iwọ li o ti rà mi pada, Oluwa Ọlọrun otitọ.
Explore O. Daf 31:5
7
O. Daf 31:23
Ẹ fẹ Oluwa, gbogbo ẹnyin enia rẹ̀ mimọ́: Oluwa npa onigbagbọ́ mọ́, o si san a li ọ̀pọlọpọ fun ẹniti nṣe igberaga.
Explore O. Daf 31:23
8
O. Daf 31:1
OLUWA, iwọ ni mo gbẹkẹ mi le: máṣe jẹ ki oju ki o tì mi: gbà mi ninu ododo rẹ.
Explore O. Daf 31:1
Home
Bible
Plans
Videos