1
O. Daf 36:9
Bibeli Mimọ
Nitori pe pẹlu rẹ li orisun ìye wà: ninu imọlẹ rẹ li awa o ma ri imọlẹ.
Compare
Explore O. Daf 36:9
2
O. Daf 36:7
Ọlọrun, iṣeun-ifẹ rẹ ti dara to! nitori na li awọn ọmọ enia yio ma gbẹkẹ wọn le abẹ ojiji iyẹ-apa rẹ.
Explore O. Daf 36:7
3
O. Daf 36:5
Oluwa, ãnu rẹ de ọrun; otitọ rẹ de awọsanma.
Explore O. Daf 36:5
4
O. Daf 36:6
Ododo rẹ dabi awọn òke Ọlọrun; idajọ rẹ dabi ibu nla: Oluwa, iwọ pa enia ati ẹranko mọ́.
Explore O. Daf 36:6
Home
Bible
Plans
Videos