1
1 Samuẹli 10:6
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ẹ̀mí OLúWA yóò sì bà lé ọ, ìwọ yóò sì sọtẹ́lẹ̀ pẹ̀lú wọn, ìwọ yóò sì di ẹni ọ̀tọ̀.
Compare
Explore 1 Samuẹli 10:6
2
1 Samuẹli 10:9
Bí Saulu ti yípadà láti fi Samuẹli sílẹ̀, Ọlọ́run yí ọkàn Saulu padà àti pé gbogbo ààmì wọ̀nyí sì wá sí ìmúṣẹ ní ọjọ́ náà.
Explore 1 Samuẹli 10:9
Home
Bible
Plans
Videos