1
Gẹnẹsisi 38:10
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ohun tí ó ń ṣe yìí burú lójú OLúWA, ó sì pa òun náà pẹ̀lú.
Compare
Explore Gẹnẹsisi 38:10
2
Gẹnẹsisi 38:9
Ṣùgbọ́n Onani mọ̀ pé àwọn ọmọ náà kì yóò jẹ́ ti òun, nítorí náà ni gbogbo ìgbà tí ó bá wọlé tọ aya arákùnrin rẹ̀ lọ, ilẹ̀ ni ó ń da nǹkan ọkùnrin rẹ̀ sí, kí ó má bá a bímọ fún arákùnrin rẹ̀.
Explore Gẹnẹsisi 38:9
Home
Bible
Plans
Videos