1
Onidajọ 21:25
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ní àwọn ọjọ́ wọ̀nyí, kò sí ọba ní ilẹ̀ Israẹli; olúkúlùkù sì ń ṣe bí ó ti tọ́ ní ojú ara rẹ̀.
Compare
Explore Onidajọ 21:25
2
Onidajọ 21:1
Àwọn ọkùnrin Israẹli ti búra ní Mispa pé: “Kò sí ẹnìkan nínú wa tí yóò fi ọmọ obìnrin rẹ̀ fún ẹ̀yà Benjamini ní ìyàwó.”
Explore Onidajọ 21:1
Home
Bible
Plans
Videos