1
Jobu 19:25
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí èmi mọ̀ pé olùdáǹdè mi ń bẹ láààyè àti pe òun ni yóò dìde dúró lórí ilẹ̀ ní ìkẹyìn
Compare
Explore Jobu 19:25
2
Jobu 19:27
Ẹni tí èmi ó rí fún ara mi, tí ojú mi ó sì wo, kì sì í ṣe ti ẹlòmíràn; ọkàn mi sì dákú ní inú mi.
Explore Jobu 19:27
Home
Bible
Plans
Videos