1
Òwe 30:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
“Gbogbo ọ̀rọ̀ Ọlọ́run jẹ́ aláìlábùkù; òun ni ààbò fún gbogbo ẹni fi í ṣe ibi ìpamọ́ wọn
Compare
Explore Òwe 30:5
2
Òwe 30:8
Mú èké ṣíṣe àti irọ́ jìnnà sí mi; má ṣe fún mi ní òsì tàbí ọrọ̀, ṣùgbọ́n fún mi ní oúnjẹ òòjọ́ mi nìkan
Explore Òwe 30:8
Home
Bible
Plans
Videos