1
Saamu 107:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ẹ fi ọpẹ́ fún OLúWA, nítorí tí ó ṣeun; nítorí ìfẹ́ rẹ̀ dúró láéláé.
Compare
Explore Saamu 107:1
2
Saamu 107:20
Ó rán ọ̀rọ̀ rẹ̀, ara wọn sì dá ó sì yọ wọ́n nínú isà òkú.
Explore Saamu 107:20
3
Saamu 107:8-9
Ẹ jẹ́ kí wọn máa yin OLúWA nítorí ìṣeun ìfẹ́ rẹ̀ àti nítorí iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ sí àwọn ọmọ ènìyàn, Nítorí tí ó tẹ́ ìfẹ́ ọkàn lọ́run ó sì fi ìre fún ọkàn tí ebi ń pa.
Explore Saamu 107:8-9
4
Saamu 107:28-29
Nígbà náà wọ́n ń kígbe sókè sí OLúWA nínú ìdààmú wọn, ó sì mú wọn jáde nínú ìṣòro wọn. Ó sọ ìjì di ìdákẹ́rọ́rọ́ bẹ́ẹ̀ ni ríru omi rẹ̀ dúró jẹ́ẹ́
Explore Saamu 107:28-29
5
Saamu 107:6
Ní ìgbà náà, wọ́n kígbe sókè sí OLúWA nínú ìdààmú wọn, ó sì yọ wọ́n kúrò nínú ìrora wọn
Explore Saamu 107:6
6
Saamu 107:19
Nígbà náà wọ́n kígbe sí OLúWA nínú ìṣòro wọn, ó sì yọ wọ́n nínú ìdààmú wọn
Explore Saamu 107:19
7
Saamu 107:13
Ní ìgbà náà wọ́n ké pe OLúWA nínú ìdààmú wọn, ó sì gbà wọ́n nínú ìṣòro wọn
Explore Saamu 107:13
Home
Bible
Plans
Videos