1
Saamu 13:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ṣùgbọ́n mo gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ rẹ tí kì í kùnà; ọkàn mi ń yọ̀ nínú ìgbàlà rẹ.
Compare
Explore Saamu 13:5
2
Saamu 13:6
Èmi ó máa kọrin sí OLúWA, nítorí ó dára sí mi.
Explore Saamu 13:6
3
Saamu 13:1
Yóò ti pẹ́ tó, OLúWA? Ìwọ o ha gbàgbé mi títí láé? Yóò tí pẹ́ tó tí ìwọ yóò máa fi ojú rẹ pamọ́ fún mi?
Explore Saamu 13:1
4
Saamu 13:2
Yóò ti pẹ́ tó tí èmi ó máa bá èrò mi jà, àti ní ojoojúmọ́ ni èmi ń ní ìbànújẹ́ ní ọkàn mi? Yóò ti pẹ́ tó tí àwọn ọ̀tá mi yóò máa borí mi?
Explore Saamu 13:2
Home
Bible
Plans
Videos