1
Saamu 137:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ní ẹ̀bá odò Babeli, níbẹ̀ ni àwa gbé jókòó àwa sì sọkún nígbà tí àwa rántí Sioni.
Compare
Explore Saamu 137:1
2
Saamu 137:3-4
Nítorí pé níbẹ̀ ni àwọn tí ó kó wa ní ìgbèkùn béèrè orin lọ́wọ́ wa, àti àwọn tí ó ni wá lára béèrè ìdárayá wí pé; ẹ kọ orin Sioni kan fún wa. Àwa ó ti ṣe kọ orin OLúWA ní ilẹ̀ àjèjì
Explore Saamu 137:3-4
Home
Bible
Plans
Videos