1
Saamu 146:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ìbùkún ni fún ẹni tí Ọlọ́run Jakọbu ń ṣe ìrànlọ́wọ́ rẹ̀ tí ìrètí rẹ̀ wà nínú OLúWA Ọlọ́run rẹ̀.
Compare
Explore Saamu 146:5
2
Saamu 146:3
Ẹ má ṣe ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú àwọn ọmọ-aládé, àní, ọmọ ènìyàn, lọ́wọ́ ẹni tí kò sí ìrànlọ́wọ́.
Explore Saamu 146:3
3
Saamu 146:7-8
Ẹni tí ń ṣe ìdájọ́ àwọn tí a ni lára tí ó fi oúnjẹ fún àwọn tí ebi ń pa OLúWA, tú àwọn oǹdè sílẹ̀ (ẹlẹ́wọ̀n) OLúWA mú àwọn afọ́jú ríran, OLúWA, gbé àwọn tí a rẹ̀ sílẹ̀ ga, OLúWA fẹ́ràn àwọn olódodo.
Explore Saamu 146:7-8
4
Saamu 146:6
Ẹni tí ó dá ọ̀run àti ayé, òkun àti ohun gbogbo tí ń bẹ nínú wọn, ẹni tí ó pa òtítọ́ mọ́ títí ayé.
Explore Saamu 146:6
5
Saamu 146:9
OLúWA ń dá ààbò bo àwọn àlejò ó sì ń dá àwọn aláìní baba àti opó sí ṣùgbọ́n ó ba ọ̀nà àwọn ènìyàn búburú jẹ́.
Explore Saamu 146:9
Home
Bible
Plans
Videos