1
Saamu 148:13
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ẹ jẹ́ kí wọn kí ó yin orúkọ OLúWA nítorí orúkọ rẹ̀ nìkan ni ó ní ọlá ògo rẹ̀ kọjá ayé àti ọ̀run
Compare
Explore Saamu 148:13
2
Saamu 148:5
Ẹ jẹ́ kí wọn kí ó yin orúkọ OLúWA nítorí ó pàṣẹ a sì dá wọn
Explore Saamu 148:5
3
Saamu 148:1
Ẹ fi ìyìn fún OLúWA. Ẹ fi ìyìn fún OLúWA láti ọ̀run wá, Ẹ fi ìyìn fún un níbi gíga.
Explore Saamu 148:1
Home
Bible
Plans
Videos