1
Saamu 19:14
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ẹnu mi àti àṣàrò ọkàn mi kí ó jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà ní ojú rẹ, Ìwọ OLúWA àpáta mi, àti Olùdáǹdè mi.
Compare
Explore Saamu 19:14
2
Saamu 19:7
Pípé ni òfin OLúWA, ó ń yí ọkàn padà. Ẹ̀rí OLúWA dánilójú, ó sọ òpè di ọlọ́gbọ́n.
Explore Saamu 19:7
3
Saamu 19:1
Àwọn ọ̀run ń sọ nípa ti ògo Ọlọ́run; Àwọsánmọ̀ ń sọ nípa ti iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.
Explore Saamu 19:1
4
Saamu 19:8
Ìlànà OLúWA tọ̀nà, ó ń fi ayọ̀ fún ọkàn. Àṣẹ OLúWA ni mímọ́, ó ń fi ìmọ́lẹ̀ fún ojú.
Explore Saamu 19:8
5
Saamu 19:9
Ìbẹ̀rù OLúWA mọ́, ó ń faradà títí láéláé. Ìdájọ́ OLúWA dájú òdodo ni gbogbo wọn.
Explore Saamu 19:9
Home
Bible
Plans
Videos