1
Saamu 25:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
ṣe amọ̀nà mi nínú òtítọ́ ọ̀ rẹ, kí o sì kọ́ mi, Nítorí ìwọ ni Ọlọ́run ìgbàlà mi; ìwọ ni mo dúró tì ní gbogbo ọjọ́.
Compare
Explore Saamu 25:5
2
Saamu 25:4
Fi ọ̀nà rẹ hàn mí, OLúWA, kọ mi ní ipa tìrẹ
Explore Saamu 25:4
3
Saamu 25:14
OLúWA fi ọkàn tán, àwọn tí o bẹ̀rù u rẹ̀; ó sọ májẹ̀mú rẹ̀ di mí mọ̀ fún wọn.
Explore Saamu 25:14
4
Saamu 25:7
Má ṣe rántí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ìgbà èwe mi tàbí ìrékọjá mi; gẹ́gẹ́ bí i ìfẹ́ ẹ rẹ̀ rántí mi nítorí tí ìwọ dára, Ìwọ! OLúWA.
Explore Saamu 25:7
5
Saamu 25:3
Ẹni tí ó dúró tì ọ́ ojú kì yóò tì í, àwọn tí ń ṣẹ̀ láìnídìí ni kí ojú kí ó tì.
Explore Saamu 25:3
Home
Bible
Plans
Videos