1
Saamu 34:18
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
OLúWA súnmọ́ etí ọ̀dọ̀ àwọn oníròbìnújẹ́ ọkàn; ó sì gba irú àwọn tí í ṣe oníròra ọkàn là.
Compare
Explore Saamu 34:18
2
Saamu 34:4
Èmi wá OLúWA, ó sì dá mi lóhùn; Ó sì gbà mí kúrò nínú ìbẹ̀rù mi gbogbo.
Explore Saamu 34:4
3
Saamu 34:19
Ìpọ́njú àwọn olódodo pọ̀, ṣùgbọ́n OLúWA gbà wọ́n kúrò nínú gbogbo rẹ̀.
Explore Saamu 34:19
4
Saamu 34:8
Tọ́ ọ wò kí o sì rí i wí pé OLúWA dára; ẹni ayọ̀ ni ọkùnrin náà tí ó gbẹ́kẹ̀lé ààbò nínú rẹ̀.
Explore Saamu 34:8
5
Saamu 34:5
Wọ́n wò ó, ìmọ́lẹ̀ sì mọ́ wọn; ojú kò sì tì wọ́n.
Explore Saamu 34:5
6
Saamu 34:17
Nígbà tí olódodo bá ké fún ìrànlọ́wọ́, OLúWA a máa gbọ́, a sì yọ wọ́n jáde láti inú gbogbo wàhálà wọn.
Explore Saamu 34:17
7
Saamu 34:7
Angẹli OLúWA yí àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀ ká ó sì gbà wọ́n.
Explore Saamu 34:7
8
Saamu 34:14
Yà kúrò nínú ibi kí o sì ṣe rere; wá àlàáfíà, kí o sì lépa rẹ̀.
Explore Saamu 34:14
9
Saamu 34:13
Pa ahọ́n rẹ̀ mọ́ kúrò nínú ibi àti ètè rẹ̀ kúrò ní ẹ̀tàn sísọ.
Explore Saamu 34:13
10
Saamu 34:15
Ojú OLúWA ń bẹ lára àwọn olódodo; etí i rẹ̀ sì ṣí sí ẹkún wọn.
Explore Saamu 34:15
11
Saamu 34:3
Gbé OLúWA ga pẹ̀lú mi; kí ẹ sì jẹ́ kí a jọ gbé orúkọ rẹ̀ lékè.
Explore Saamu 34:3
Home
Bible
Plans
Videos