1
Saamu 7:17
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Èmi ó fi ọpẹ́ fún OLúWA nítorí òdodo rẹ̀, Èmi ó kọrin ìyìn sí OLúWA Ọ̀gá-ògo jùlọ.
Compare
Explore Saamu 7:17
2
Saamu 7:10
Ààbò mi ń bẹ lọ́dọ̀ Ọlọ́run, ẹni tí ń ṣe ìgbàlà òtítọ́ ní àyà.
Explore Saamu 7:10
3
Saamu 7:11
Ọlọ́run ni onídàájọ́ òtítọ́, Ọlọ́run tí ń sọ ìrunú rẹ̀ ní gbogbo ọjọ́.
Explore Saamu 7:11
4
Saamu 7:9
Ọlọ́run Olódodo, Ẹni tí ó ń wo inú àti ọkàn, tí ó ń mú òpin sí ìwà ipá ẹni búburú tí ó sì ń pa àwọn olódodo mọ́.
Explore Saamu 7:9
5
Saamu 7:1
OLúWA Ọlọ́run mi, ààbò mi wà nínú rẹ; gba mí là kí o sì tú mi sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn tó ń lé mi
Explore Saamu 7:1
Home
Bible
Plans
Videos