1
Saamu 84:11
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí OLúWA Ọlọ́run jẹ́ òòrùn àti asà; OLúWA fún ni ní ojúrere àti ọlá; kò sí ohun rere kan tí yóò fàsẹ́yìn fún àwọn tí ó rìn ní àìlábùkù.
Compare
Explore Saamu 84:11
2
Saamu 84:10
Dídára ní ọjọ́ kan ní ààfin rẹ ju ẹgbẹ̀rún ọjọ́ lọ; èmi o kúkú máa ṣe aṣọ́nà nínú ilé Ọlọ́run mi jù láti gbé ní àgọ́ àwọn ènìyàn búburú.
Explore Saamu 84:10
3
Saamu 84:5
Ìbùkún ni fún àwọn tí agbára wọn wà nínú rẹ àwọn tí wọ́n gbé ọkàn lé bíbẹ ibi mímọ́ wò.
Explore Saamu 84:5
4
Saamu 84:2
Ọkàn mi ń ṣàfẹ́rí nítòótọ́ ó tilẹ̀ pòǹgbẹ fún àgbàlá OLúWA àyà mi àti ara mi ń kọrin ayọ̀ sí Ọlọ́run alààyè.
Explore Saamu 84:2
Home
Bible
Plans
Videos