1
Saamu 89:15
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ìbùkún ni fún àwọn ènìyàn tí wọn mọ ohùn ayọ̀ nì, OLúWA wọ́n ó máa rìn ní ìmọ́lẹ̀ ojú rẹ.
Compare
Explore Saamu 89:15
2
Saamu 89:14
Òdodo àti òtítọ́ ni ìpìlẹ̀ ìtẹ́ rẹ: ìdúró ṣinṣin ìfẹ́ àti òtítọ́ ń lọ síwájú rẹ.
Explore Saamu 89:14
3
Saamu 89:1
Èmi kọrin títóbi ìfẹ́ OLúWA títí láé; pẹ̀lú ẹnu mi ní èmi yóò jẹ́ kí a mọ òtítọ́ rẹ láti ìran dé ìran.
Explore Saamu 89:1
4
Saamu 89:8
OLúWA Ọlọ́run alágbára, ta ló dàbí rẹ ìwọ jẹ́ alágbára, OLúWA, òtítọ́ rẹ sì yí ọ ká.
Explore Saamu 89:8
Home
Bible
Plans
Videos