1
Sekariah 6:12
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
YCB
Sì sọ fún un pé: ‘Báyìí ni OLúWA àwọn ọmọ-ogun sọ wí pé, wo ọkùnrin náà ti orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ẹ̀ka; yóò sì yọ ẹ̀ka láti abẹ́ rẹ̀ wá, yóò si kọ́ tẹmpili OLúWA wa.
Compare
Explore Sekariah 6:12
2
Sekariah 6:13
Òun ni yóò sì kọ́ tẹmpili OLúWA òun ni yóò sì wọ̀ ní ògo, yóò sì jókòó, yóò sì jẹ ọba lórí ìtẹ́ rẹ̀; òun ó sì jẹ́ àlùfáà lórí ìtẹ́ rẹ̀; ìmọ̀ àlàáfíà yóò sì wá láàrín àwọn méjèèjì.’
Explore Sekariah 6:13
Home
Bible
Plans
Videos