YouVersion Logo
Search Icon

SAMUẸLI KEJI 1:12

SAMUẸLI KEJI 1:12 YCE

Wọ́n ṣọ̀fọ̀, wọ́n sọkún, wọ́n sì gbààwẹ̀ títí di ìrọ̀lẹ́; nítorí Saulu ati Jonatani, ọmọ rẹ̀, ati àwọn ọmọ Israẹli, eniyan OLUWA nítorí pé ọpọlọpọ wọn ni wọ́n ti pa lójú ogun.

Video for SAMUẸLI KEJI 1:12