YouVersion Logo
Search Icon

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 12:7

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 12:7 YCE

Angẹli Oluwa kan bá yọ dé, ìmọ́lẹ̀ sì tàn ninu ilé náà. Angẹli náà bá rọra lu Peteru lẹ́gbẹ̀ẹ́, ó jí i, ó ní, “Dìde kíá.” Àwọn ẹ̀wọ̀n tí wọ́n fi de Peteru bá yọ bọ́ kúrò ní ọwọ́ rẹ̀

Video for ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 12:7

Free Reading Plans and Devotionals related to ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 12:7