YouVersion Logo
Search Icon

ÀWỌN ADÁJỌ́ 16:20

ÀWỌN ADÁJỌ́ 16:20 YCE

Ó wí fún un pé, “Samsoni! Àwọn ará Filistia ti dé.” Samsoni bá jí láti ojú oorun, ó ní, “N óo lọ bí mo ti máa ń ṣe tẹ́lẹ̀, n óo sì gba ara mi lọ́wọ́ wọn.” Kò mọ̀ pé OLUWA ti fi òun sílẹ̀.

Video for ÀWỌN ADÁJỌ́ 16:20

Free Reading Plans and Devotionals related to ÀWỌN ADÁJỌ́ 16:20